Revelation 2:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
O tún ní àwọn kan tí àwọn náà gba ẹ̀kọ́ àwọn Nikolaiti.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni iwọ si ní awọn ti o gbà ẹkọ awọn Nikolaitani pẹlu, ohun ti mo korira.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni ìwọ sì ní àwọn tí ó gbá ẹ̀kọ́ àwọn Nikoláétanì pẹ̀lú, ohun tí mo kórìíra.