Revelation 2:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo fún un ní àkókò kí ó ronupiwada, ṣugbọn kò fẹ́ ronupiwada kúrò ninu ìwà àgbèrè rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi si fi sã fun u lati ronupiwada; kò si fẹ ronupiwada agbere rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi fi àkókò fún un, láti ronúpìwàdà; ṣùgbọ́n òun kò fẹ́ ronúpìwàdà àgbèrè rẹ̀.