Revelation 21:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọn kò ní ti àwọn ìlẹ̀kùn ìlú náà ní gbogbo ọ̀sán; òru kò sì ní sí níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A kì yio si sé awọn ẹnubode rẹ̀ rara li ọsán: nitori kì yio si oru nibẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A kì yóò sì ṣé àwọn ẹnu-bodè rẹ̀ rárá ní ọ̀sán: nítorí ki yóò si òru níbẹ̀.