Revelation 5:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo sì rí angẹli alágbára kan tí ń ké pẹlu ohùn rara pé, “Ta ni ó yẹ láti ṣí ìwé náà, ati láti tú èdìdì rẹ̀?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo si ri angẹli alagbara kan, o nfi ohùn rara kede pe, Tali o yẹ lati ṣí iwe na, ati lati tú èdidi rẹ̀?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mó sì rí ańgẹ́lì alágbára kan, ó ń fi ohùn rara kéde pé, “Táni ó yẹ láti ṣí ìwé náà, àti láti tu èdìdì rẹ̀?”