Romans 1:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí a bá wo inú Ìwé Mímọ́, a óo rí i pé àwọn wolii ti kéde ìyìn rere náà tẹ́lẹ̀ rí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
(Ti o ti ṣe ileri tẹlẹ rí ninu iwe-mimọ́, lati ọwọ awọn woli rẹ̀),
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìyìnrere tí a ti pinnu láti ẹnu àwọn wòlíì nínú ìwé Mímọ́ láti ìgbà pípẹ́ ṣáájú ìsinsin yìí.