Romans 1:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
nípa ẹni tí a ti rí oore-ọ̀fẹ́ gbà, tí a sì gba iṣẹ́ òjíṣẹ́ ní orúkọ rẹ̀, pé kí gbogbo eniyan lè gba Jesu gbọ́, kí wọ́n sì gbọ́ràn sí i lẹ́nu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati ọdọ ẹniti awa ri ore-ọfẹ ati iṣẹ aposteli gbà, fun igbọràn igbagbọ́ lãrin gbogbo orilẹ-ède, nitori orukọ rẹ̀:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti ọdọ ẹni tí àwa rí oore-ọ̀fẹ́ àti jíjẹ́ Àpósítélì gbà, láti wàásù fún gbogbo ènìyàn orílẹ̀-èdè kí wọn kí ó lè wá sínú ìgbàgbọ́ èyíni ní orúkọ rẹ̀.