Romans 1:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀yin tí mò ń kọ ìwé yìí sí náà wà lára àwọn tí Jesu Kristi pè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Larin awọn ẹniti ẹnyin pẹlu ti a pè lati jẹ ti Jesu Kristi:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀yin pẹ̀lú si wa lára àwọn tí a pè sọ́dọ̀ Jésù Kírísítì.