Romans 10:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Aisaya pàápàá kò jẹ́ kí ọ̀rọ̀ kọ́ òun lẹ́nu, ó ní, “Àwọn tí kò wá mi ni wọ́n rí mi, àwọn tí kò bèèrè mi ni mo fi ara hàn fún.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Isaiah tilẹ laiya, o si wipe, Awọn ti kò wá mi ri mi; awọn ti kò bère mi li a fi mi hàn fun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Ìsáià tilẹ̀ láyà, ó wí pé, “Àwọn tí kò wá mi rí mi; Àwọn tí kò béèrè mi ni a fi mí hàn fún.”