Romans 10:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mose kọ sílẹ̀ báyìí nípa ìdáláre tí Òfin lè fúnni pé, “Ẹnikẹ́ni tí ó bá pa wọ́n mọ́, yóo ti ipa wọn rí ìyè.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose sá kọ̀we rẹ̀ pe, ẹniti o ba ṣe ododo ti iṣe ti ofin, yio yè nipa rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé Mósè kọ ọ́ pé, “Kí ènìyàn tó lè rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ àti ìgbàlà (nípa òfin) gbà, ó ní láti ja àjàṣẹ́gun nínú gbogbo ìdánwò, kí ó sì wà láì dá ẹ̀ṣẹ̀ kan soso nínú gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀.”