Romans 15:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó tún sọ pé, “Ẹ yin Oluwa, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè kí gbogbo eniyan yìn ín.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati pẹlu, Ẹ yìn Oluwa gbogbo ẹnyin Keferi; ẹ si kokikí rẹ̀, ẹnyin enia gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti pẹ̀lú, “Ẹyin Olúwa, gbogbo ẹ̀yin aláìkọlà; ẹ kọ orin ìyìn sí, ẹ̀yin ènìyàn gbogbo.”