Romans 15:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Aisaya tún sọ pé, “Gbòǹgbò kan yóo ti ìdílé Jese yọ, yóo yọ láti pàṣẹ fún àwọn orílẹ̀-èdè, nítorí lọ́dọ̀ rẹ̀ ni ìrètí àwọn orílẹ̀-èdè wà.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Isaiah si tún wipe, Gbòngbo Jesse kan mbọ̀ wá, ati ẹniti yio dide ṣe akoso awọn Keferi; on li awọn Keferi yio ni ireti si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àìṣáyà sì tún wí pé, “Gbòngbò Jésè kan ń bọ̀ wá, òun ni ẹni tí yóò dìde ṣe àkóso àwọn aláìkọlà; Àwọn aláìkọlà yóò ní ìrètí nínú rẹ̀.”