Romans 15:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn àníyàn mi rí bí ọ̀rọ̀ tí ó wà ní àkọsílẹ̀ pé, “Àwọn ẹni tí kò gbọ́ nípa rẹ̀ rí, yóo rí i. Ọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ yóo yé àwọn tí kò gbúròó rẹ̀ rí.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn gẹgẹ bi a ti kọ ọ pe, Awọn ẹniti a kò ti sọ̀rọ rẹ̀ fun, nwọn ó ri i: ati awọn ti kò ti gbọ́, òye yio yé wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n, gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé: “Àwọn tí kò tí ì sọ òrọ̀ rẹ̀ fún yóò rí i, yóò sì yé àwọn tí kò tí ì gbọ́ ọ rí.”