Romans 15:32 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Èyí yóo jẹ́ kí n fi ayọ̀ wá sọ́dọ̀ yín, bí Ọlọrun bá fẹ́, tí ọkàn mi yóo fi balẹ̀ nígbà tí mo bá wà lọ́dọ̀ yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki emi ki o le fi ayọ̀ tọ̀ nyin wá nipa ifẹ Ọlọrun, ati ki emi le ni itura pọ pẹlu nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, nípa ìfẹ́ Ọlọ́run kí èmi le fi ayọ̀ tọ̀ yín wa, kí pọ̀ pẹ̀lú yín ní ìtura.