Romans 16:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ kí Apele, akikanju onigbagbọ. Ẹ kí àwọn ará ilé Arisitobulu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ ki Apelle ẹniti a mọ̀ daju ninu Kristi. Ẹ kí awọn arãle Aristobulu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ kí Ápẹ́lẹ́sì, ẹni tí a mọ̀ dájú nínú Kírísítì. Ẹ kí gbogbo àwọn ará nílé Árísítóbúlúsì.