Romans 8:36 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó wà ní àkọsílẹ̀ pé, “Nítorí rẹ a wà ninu ewu ikú lojoojumọ, wọ́n sì ṣe wá bí aguntan tí wọ́n fẹ́ lọ pa.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gẹgẹ bi a ti kọ ọ pe, Nitori rẹ li a ṣe npa wa kú li gbogbo ọjọ; a nkà wa si bi agutan fun pipa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ kọ́, nítorí ìwé mímọ́ sọ fún wa pé: “Nítorí yín àwa ní láti múra tan fún ikú nígbàkúgbà. Àwa dàbí àgùntàn tí ń dúró de pípa.”