Romans 9:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní ibìkan náà tí a ti sọ fún wọn rí pé, ‘Ẹ kì í ṣe eniyan mi mọ́’ ni a óo ti pè wọ́n ní ọmọ Ọlọrun alààyè.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si ṣe, ni ibi ti a gbé ti sọ fun wọn pe, Ẹnyin kì iṣe enia mi, nibẹ̀ li a o gbé pè wọn li ọmọ Ọlọrun alãye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yóò sì ṣe, “Ní ibi ti a gbé ti sọ fún wọn pé, ‘ẹ̀yin kì í ṣe ènìyàn mi,’ níbẹ̀ ni a ó gbé ti sọ fún wọn pé, ẹ̀yin kì í ṣe ènìyàn mi, níbẹ̀ ni a ó gbé pè wọ́n ní ‘ọmọ Ọlọ́run alààyè.’ ”