Romans 9:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Aisaya náà kéde nípa Israẹli pé, “Bí àwọn ọmọ Israẹli tilẹ̀ pọ̀ bí iyanrìn òkun, sibẹ díẹ̀ péré ni a óo gbà là.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Isaiah si kigbe nitori Israeli pe, Bi iye awọn ọmọ Israeli bá ri bi iyanrin okun, apakan li a ó gbala.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìsáíà sì kí gbe nnítorí Ísírẹ́lì pé: “Bí iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bá rí bí iyanrìn etí òkun, apákan ni ó gbàlà.