Ruth 4:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Boasi bá ṣú Rutu lópó, Rutu sì di aya rẹ̀. Nígbà tí Boasi bá a lòpọ̀, ó lóyún, ó bí ọmọkunrin kan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Boasi si mú Rutu, on si di aya rẹ̀; nigbati o si wọle tọ̀ ọ, OLUWA si mu ki o lóyun, o si bi ọmọkunrin kan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báyìí ni Bóásì ṣe mú Rúùtù, tí ó sì di aya rẹ̀. Nígbà náà ni ó wọlé tọ aya rẹ̀, OLÚWA sì mú kí ó lóyùn, ó sì bí ọmọ ọkùnrin kan.