Ruth 4:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, nígbà tí ìbátan náà wí fún Boasi pé, “Rà á bí o bá fẹ́.” Ó bọ́ bàtà ẹsẹ̀ rẹ̀ fún Boasi,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni ibatan na wi fun Boasi pe, Rà a fun ara rẹ. O si bọ́ bàta rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, nígbà tí ọkùnrin náà sọ fún Bóásì wí pé, “Ìwọ rà á fúnràrẹ,” ó yọ bàtà rẹ̀ kúrò ní ẹsẹ̀ rẹ̀.