Song of Solomon 2:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn igi ọ̀pọ̀tọ́ tí ń so èso, àjàrà tí ń tanná, ìtànná wọn sì ń tú òórùn dídùn jáde. Dìde, olùfẹ́ mi, arẹwà mi, jẹ́ kí á máa lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Igi ọ̀pọtọ so eso titun, awọn àjara funni ni õrun daradara nipa itanná wọn. Dide, olufẹ mi, arẹwà mi kanna, ki o si jade kalọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Igi ọ̀pọ̀tọ́ mú èso tuntun jáde Àwọn àjàrà nípa ìtànná wọn fún ni ní òórùn dídùn Dìde, wá, Olùfẹ́ mi; Arẹwà mi nìkan ṣoṣo, wá pẹ̀lú mi.”