Song of Solomon 2:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo kìlọ̀ fun yín, ẹ̀yin ọmọbinrin Jerusalẹmu, ní orúkọ egbin, ati ti àgbọ̀nrín pé, ẹ kò gbọdọ̀ jí ìfẹ́ títí yóo fi wù ú láti jí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo fi awọn abo egbin, ati awọn abo agbọnrin igbẹ fi nyin bú, ẹnyin ọmọbinrin Jerusalemu, ki ẹ máṣe rú olufẹ mi soke, ki ẹ má si ṣe ji i, titi yio fi wù u.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀yin ọmọbìnrin Jérúsálẹ́mù, mo fi abo egbin àti ọmọ àgbọ̀nrín fi yín bú Kí ẹ má ṣe ru ìfẹ́ olùfẹ́ mi sókè Kí ẹ má sì ṣe jí i títí yóò fi wù ú