Song of Solomon 3:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó fi fadaka ṣe àwọn ẹsẹ̀ ìjókòó rẹ̀, ó fi wúrà ṣe ẹ̀yìn rẹ̀, Aṣọ elése-àlùkò tí àwọn ọmọbinrin Jerusalẹmu hun ni ó fi ṣe tìmùtìmù ìjókòó rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O fi fadaka ṣe ọwọ̀n rẹ̀, o fi wura ṣe ibi ẹhin rẹ̀, o fi elese aluko ṣe ibujoko rẹ̀, inu rẹ̀ li o fi ifẹ tẹ́ nitori awọn ọmọbinrin Jerusalemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó fi fàdákà ṣe òpó rẹ̀ Ó fi wúrà ṣe ibi ẹ̀yìn rẹ̀ Ó fi elésè àlùkò ṣe ibùjókòó rẹ̀, Inú rẹ̀ ni ó kọ àwọn ọ̀rọ̀ ìfẹ́ wọ̀nyí sí “Pẹ̀lú ìfẹ́ láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọbìnrin Jérúsálẹ́mù.”