Song of Solomon 3:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí ló ń jáde bọ̀ láti inú aṣálẹ̀ yìí, tí ó dàbí òpó èéfín, tí ó kún fún òórùn dídùn òjíá ati turari, pẹlu òórùn dídùn àtíkè àwọn oníṣòwò?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Tani eyi ti nti ijù jade wá bi ọwọ̀n ẽfin, ti a ti fi ojia ati turari kùn lara, pẹlu gbogbo ipara olõrun oniṣowo?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ta ni ẹni tí ń ti ijù jáde wá bí ìkuku èéfín tí a ti fi òjíá àti tùràrí kùn lára pẹ̀lú gbogbo ètù olóòórùn oníṣòwò?