Song of Solomon 3:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wò ó! Solomoni ni wọ́n ń gbé bọ̀, lórí ìtẹ́ rẹ̀, ọgọta akọni ọkunrin, lára àwọn akọni Israẹli, ni ó yí ìtẹ́ rẹ̀ ká.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wo akete rẹ̀, ti iṣe ti Solomoni; ọgọta akọni enia li o yi i ka ninu awọn akọni Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wò ó! Àkéte rẹ̀ tí í ṣe ti Sólómónì, Àwọn akọni ọgọ́ta ni ó wà yí i ká, Àwọn akọni Ísírẹ́lì,