Song of Solomon 3:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo wọn dira ogun pẹlu idà, akọni sì ni wọ́n lójú ogun. Olukuluku dira pẹlu idà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀, nítorí ìdágìrì ọ̀gànjọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo wọn li o di idà mu, nwọn gbọ́n ọgbọ́n ogun: olukulùku kọ́ idà rẹ̀ nitori ẹ̀ru li oru.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo wọn ni ó mú idà lọ́wọ́, gbogbo wọn ní ìmọ̀ nínú ogun, Idà oníkálùkù wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀, Wọ́n múra sílẹ̀ fún ìdágìrì òru