Song of Solomon 4:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
igi nadi ati Safironi, Kalamusi ati Sinamoni, pẹlu oríṣìíríṣìí igi turari, igi òjíá, ati ti aloe, ati àwọn ojúlówó turari tí òórùn wọn dára jùlọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nardi ati saffroni; kalamusi, kinnamoni, pẹlu gbogbo igi turari; ojia ati aloe, pẹlu gbogbo awọn olori olõrun didùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nádì àti Ṣáfírónì, kálámúsì àti kínámónì, àti gbogbo igi olóòórùn dídùn, òjíá àti álóé pẹ̀lú irú wọn.