Song of Solomon 4:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Máa bá mi bọ̀ láti òkè Lẹbanoni, iyawo mi, máa bá mi bọ̀ láti òkè Lẹbanoni. Kúrò ní ṣóńṣó òkè Amana, kúrò lórí òkè Seniri ati òkè Herimoni, kúrò ninu ihò kinniun, ati ibi tí àwọn ẹkùn ń gbé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki a lọ kuro ni Lebanoni, iyawo mi, ki a lọ kuro ni Lebanoni: wò lati ori òke Amana, lati ori òke Ṣeniri ati Hermoni, lati ibi ihò kiniun, lati òke awọn ẹkùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí a lọ kúrò ní Lẹ́bánónì, ìyàwó mi, ki a lọ kúrò ní Lẹ́bánónì. Àwa wò láti orí òkè Ámánà, láti orí òkè ti Ṣénírì, àti téńté Hérímónì, láti ibi ihò àwọn kìnnìún, láti orí òkè ńlá àwọn ẹkùn.