Song of Solomon 6:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Yíjú kúrò lọ́dọ̀ mi, nítorí wọn kò jẹ́ kí n gbádùn. Irun orí rẹ dàbí ọ̀wọ́ ewúrẹ́ ninu agbo, tí ń sọ̀kalẹ̀ ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè Gileadi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mu oju rẹ kuro lara mi nitori nwọn bori mi: irun rẹ si dabi ọwọ́ ewurẹ ti o dubulẹ ni Gileadi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yí ojú rẹ kúrò lára mi; nítorí ojú rẹ borí mi. Irun rẹ rí bí i ọ̀wọ́ ewúrẹ́ tí ó sọ̀kalẹ̀ wá láti Gílíádì.