Song of Solomon 8:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Èmi ni mo ni ọgbà àjàrà tèmi, ìwọ Solomoni lè ní ẹgbẹrun ìwọ̀n owó fadaka, kí àwọn tí wọn yá ọgbà sì ní igba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọgba-àjara mi, ti iṣe temi, o wà niwaju mi: iwọ Solomoni yio ni ẹgbẹrun fadaka, ati awọn ti nṣọ eso na yio ni igba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ọgbà àjàrà mi jẹ́ tèmi, ó wà fún mi; ẹgbẹ̀rún ṣékélì jẹ́ tìrẹ, ìwọ Sólómónì, igba sì jẹ́ ti àwọn alágbàtọ́jú èso.