Song of Solomon 8:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìwọ tí ò ń gbé inú ọgbà, àwọn ẹlẹgbẹ́ mi ń dẹtí, jẹ́ kí n gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ti ngbe inu ọgbà, awọn ẹgbẹ rẹ fetisi ohùn rẹ: mu mi gbọ́ ọ pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ tí ń gbé inú ọgbà, àwọn ọ̀rẹ́ rẹ dẹtí sí ohùn rẹ, Jẹ́ kí èmi náà gbọ́ ohùn rẹ!