Titus 2:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Báyìí ni kí o máa wí fún wọn, kí o máa fi gbà wọ́n níyànjú kí o sì máa bá wọn wí nígbà gbogbo pẹlu àṣẹ. Má gbà fún ẹnikẹ́ni láti fojú tẹmbẹlu rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nkan wọnyi ni ki iwọ ki o mã sọ, ki o si ma gbà-ni-niyanju, ki o si mã fi aṣẹ gbogbo ba-ni-wi. Máṣe jẹ ki ẹnikẹni ki o gàn ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn nǹkan wọ̀nyí ni kí ìwọ kí ó máa kọ wọn. Gba ni níyànjú kí ó sì máa fi gbogbo àṣẹ bániwí. Máe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni kí ó gàn ọ́.