Titus 2:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí gbolohun ẹnu rẹ jẹ́ ti ọmọlúwàbí, tí ẹnìkan kò ní lè fi bá ọ wí. Èyí yóo mú ìtìjú bá ẹni tí ó bá fẹ́ ṣe alátakò nígbà tí kò bá rí ohun burúkú kan sọ nípa wa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọ̀rọ ti o yè kõro, ti a kò le da lẹbi; ki oju ki o tì ẹniti o nṣòdi, li aini ohun buburu kan lati wi si wa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
jẹ́ ẹni tó jáfáfà nínú ọ̀rọ̀ sísọ, ẹni tí kò see tanù, kí ojú kò lé tí àwọn alátakò rẹ̀ nígbà tí wón kò bá rí ohun búburú sọ nípa rẹ̀.