Titus 3:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí mo bá rán Atemasi tabi Tukikọsi sí ọ, sa ipá rẹ láti wá sọ́dọ̀ mi ní ìlú Nikopoli, nítorí níbẹ̀ ni mo pinnu láti wà ní àkókò òtútù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati mo ba rán Artema si ọ, tabi Tikiku, yara tọ̀ mi wá ni Nikopoli: nitori ibẹ ni mo ti pinnu lati lo akoko otutu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní kété tí mo bá ti rán Àtémà tàbí Tíkíkù sí ọ, sa gbogbo ipá rẹ láti tòmíwá ní Níkópólì, nítorí mo ti pinnu láti lo ìgbà òtútù mi níbẹ̀.