Titus 3:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Sa gbogbo ipá rẹ láti ran Senasi, lọ́yà, ati Apolo lọ́wọ́ kí wọn lè bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò wọn, kí o sì rí i pé gbogbo ohun tí wọ́n nílò tẹ̀ wọ́n lọ́wọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pese daradara fun Sena amofin ati Apollo li ọ̀na àjo wọn, ki ohunkohun maṣe kù wọn kù.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sa gbogbo agbára rẹ láti ran Sénà agbẹjọ́rò àti Àpólò lọ́wọ́ nínú ìrìnàjò wọn. Rí i dájú pé wọn ní ohun gbogbo tí wọn nílò.