Zechariah 1:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Èmi OLUWA bínú sí àwọn baba ńlá yín. Nítorí náà,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa ti binu pupọ̀ si awọn baba nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“OLÚWA ti bínú sí àwọn baba ńlá yín.