Zechariah 10:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọn óo la òkun Ijipti kọjá, ìgbì rẹ̀ yóo sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Odò Naili yóo gbẹ kanlẹ̀, a óo rẹ ìgbéraga ilẹ̀ Asiria sílẹ̀, agbára óo sì kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Ijipti.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si là okun wahala ja, yio si lù riru omi ninu okun, gbogbo ibu odò ni yio si gbẹ, a o si rẹ̀ igberaga Assiria silẹ, ọpa alade Egipti yio si lọ kuro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn yóò sì la òkun wàhálà já, yóò sì lu rírú omi nínú òkun, gbogbo ibú odò ni yóò sì gbẹ, a ó sì rẹ ìgbéraga Áṣíríà ṣílẹ̀, ọ̀pá aládé Éjíbítì yóò sí lọ kúrò.