Zechariah 10:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tó bá yá, ilé Efuraimu yóo dàbí jagunjagun alágbára, inú wọn yóo sì dùn bí inú ẹni tí ó mu ọtí waini. Nígbà tí àwọn ọmọ wọn bá rí i, inú wọn yóo dùn, ọkàn wọn yóo sì yin OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Efraimu yio si ṣe bi alagbara, ọkàn wọn yio si yọ̀ bi ẹnipe nipa ọti-waini: ani awọn ọmọ wọn yio ri i, nwọn o si yọ̀, inu wọn o si dùn si Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Éfúráímù yóò sì ṣe bí alágbára, ọkàn wọn yóò sì yọ̀ bi ẹni pé nípa ọtí-wáìnì: àní àwọn ọmọ wọn yóò rí í, wọn o sì yọ̀, inú wọn ó sì dùn nínú OLÚWA.