Zechariah 10:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“N óo ṣẹ́wọ́ sí wọn, n óo sì kó wọn jọ sinu ilé. Mo ti rà wọ́n pada, nítorí náà wọn yóo tún pọ̀ bíi ti àtẹ̀yìnwá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o kọ si wọn, emi o si ṣà wọn jọ; nitori emi ti rà wọn pada: nwọn o si rẹ̀ si i gẹgẹ bi wọn ti nrẹ̀ si i ri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi ó kọ sí wọn, èmi ó sì ṣà wọ́n jọ; nítorí èmi tí rà wọ́n padà; wọn ó sì pọ̀ sí i gẹ́gẹ́ bí wọ́n tí ń pọ̀ sí í rí.