Zechariah 11:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ tẹ́tí sílẹ̀, kí ẹ gbọ́ ẹkún àwọn darandaran, nítorí ògo wọn ti díbàjẹ́. Ẹ gbọ́ bí àwọn kinniun ti ń bú ramúramù, nítorí igbó tí wọn ń gbé lẹ́bàá odò Jọdani ti parun!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohùn igbe awọn oluṣọ agutan; nitori ogo wọn bajẹ: ohùn bibu awọn ọmọ kiniun; nitori ogo Jordani bajẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbọ́ ohun igbe àwọn olùṣọ́-àgùntàn; ògo wọn bàjẹ́; gbọ́ ohùn bíbú àwọn ọmọ kìnnìún nítorí ògo Jódánì bàjẹ́.