Zechariah 2:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀yin eniyan, ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú OLUWA, nítorí ó ń jáde bọ̀ láti ibi mímọ́ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ dakẹ, gbogbo ẹran-ara niwaju Oluwa: nitori a ji i lati ibùgbe mimọ́ rẹ̀ wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀ dákẹ̀, gbogbo ẹran-ara níwájú OLÚWA: nítorí a jí i láti ibùgbé mímọ́ rẹ̀ wá.”