Zechariah 5:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo bi angẹli náà pé, “Níbo ni wọ́n ń gbé e lọ?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo si sọ fun angeli ti o mba mi sọ̀rọ pe, Nibo ni awọn wọnyi ngbe òṣuwọn efa na lọ?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo sì sọ fún ańgẹ́lì tí ó ń bá mi sọ̀rọ̀ pé, “Níbo ni àwọn wọ̀nyí ń gbé òṣùwọ̀n éfà náà lọ.”