Zechariah 5:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n ṣí ìdérí òjé tí wọ́n fi bo agbọ̀n náà kúrò lórí rẹ̀, mo rí obinrin kan tí ó jókòó sinu eefa náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Si kiyesi i, a gbe talenti ojé soke: obinrin kan si niyi ti o joko si ãrin òṣuwọn efa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sì kíyèsí i, a gbé talẹ́ńtì òjé sókè: obìnrin kan sì nìyìí tí ó jókòó sí àárin òṣùwọ̀n éfà.