Zechariah 9:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ní ilẹ̀ Hadiraki yóo jìyà, bẹ́ẹ̀ náà sì ni ìlú Damasku. Nítorí pé OLUWA ló ni àwọn ìlú Aramu, bí ó ti ni àwọn ẹ̀yà Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọ̀RỌ-ÌMỌ ọ̀rọ Oluwa ni ilẹ Hadraki, Damasku ni yio si jẹ ibi isimi rẹ̀: nitori oju Oluwa mbẹ lara enia, ati lara gbogbo ẹ̀ya Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀rọ̀ OLÚWA kọjú ìjà sí Hádírákì, Dámásíkù ni yóò sì jẹ́ ibi ìṣinmi rẹ̀; nítorí ojú OLÚWA ń bẹ lára ènìyàn, àti lára gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì.