Zechariah 9:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA yóo fara han àwọn eniyan rẹ̀, yóo ta ọfà rẹ̀ bíi mànàmáná. OLUWA Ọlọrun yóo fọn fèrè ogun yóo sì rìn ninu ìjì líle ti ìhà gúsù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa yio si fi ara rẹ̀ hàn lori wọn, ọfà rẹ̀ yio si jade lọ bi mànamána: Oluwa Ọlọrun yio si fun ipè, yio si lọ ti on ti ãjà gusù.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA yóò sì fí arahàn ní orí wọn Ọ̀kọ̀ rẹ̀ yóò tàn bí mọ̀nàmọ́ná. OLÚWA ọ̀gá-ògo yóò sì fọn ìpè, Òun yóò sì lọ nínú atẹ́gùn ìjì gúṣù.