Zephaniah 1:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ati àwọn tí ń gun orí òrùlé lọ láti bọ oòrùn, òṣùpá, ati àwọn ìràwọ̀. Wọ́n ń sin OLUWA wọ́n sì ń fi orúkọ rẹ̀ búra wọ́n sì tún ń fi oriṣa Milikomu búra;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ti nsìn ogun ọrun lori orule: awọn ti nsìn, ti nfi Oluwa bura, ti si nfi Malkomu bura;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àti àwọn tí wọn ń foríbalẹ̀ tí wọn ń sin ogun ọ̀run lórí òrùlé. Àwọn tí wọn ń sìn, tí wọ́n sì ń fi OLÚWA búra, tí wọ́n sì ń fi Mólékì búra.