Zephaniah 1:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní ọjọ́ náà, n óo jẹ àwọn tí ń fo ẹnu ọ̀nà kọjá bí àwọn abọ̀rìṣà níyà, ati àwọn tí ń fi ìwà ipá, ati olè jíjà kó nǹkan kún ilé oriṣa wọn.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ na gan li emi o bẹ̀ gbogbo awọn ti nfò le iloro wò pẹlu, ti nfi ìwà-ipá on ẹ̀tan kún ile oluwa wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ náà, èmi yóò fi ìyà jẹ gbogbo àwọn tí ó yẹra láti rìn lórí ìloro ẹnu ọ̀nà, tí wọ́n sì kún tẹ́ḿpìlì OLÚWA wọn pẹ̀lú ìwà-ipá àti ẹ̀tàn.