Zephaniah 2:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ gbé! Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé etí òkun, orílẹ̀-èdè Kereti! Ọ̀rọ̀ OLUWA ń ba yín wí, Kenaani, ilẹ̀ àwọn ará Filistia; n óo pa yín run patapata láìku ẹnìkan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Egbe ni fun awọn ẹniti ngbe agbègbe okun, orilẹ-ède awọn ara Kereti! ọ̀rọ Oluwa dojukọ nyin; iwọ Kenaani, ilẹ awọn ara Filistia, emi o tilẹ pa ọ run, ti ẹnikan kì yio gbe ibẹ̀ mọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ègbé ni fún ẹ̀yin tí ń gbé etí òkun, ẹ̀yin ènìyàn ara Kérétì; Ọ̀rọ̀ OLÚWA dojúkọ ọ́, ìwọ Kénánì, ilẹ̀ àwọn ara Fílísítíà. Èmi yóò pa yín run, ẹnìkan kò sì ní ṣẹ́kù nínú yín;