bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
/
1 Chronicles 3
1 Chronicles 3
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
← Chapter 2
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 4 →
1
WỌNYI li awọn ọmọ Dafidi, ti a bi fun u ni Hebroni; akọbi Amnoni, lati ọdọ Ahinoamu ara Jesreeli; ekeji Danieli, lati ọdọ Abigaili ara Karmeli;
2
Ẹkẹta, Absalomu ọmọ Maaka ọmọbinrin Talmai ọba Gesuri; ẹkẹrin, Adonijah ọmọ Haggiti.
3
Ẹkarun, Ṣefatiah lati ọdọ Abitali; ẹkẹfa Itreamu lati ọdọ Ẹgla aya rẹ̀.
4
Awọn mẹfa wọnyi li a bi fun u ni Hebroni; nibẹ li o si jọba li ọdun meje on oṣù mẹfa: ati ni Jerusalemu li o jọba li ọdun mẹtalelọgbọn.
5
Wọnyi li a si bi fun u ni Jerusalemu; Ṣimea, ati Ṣobabu, ati Natani, ati Solomoni, mẹrin, lati ọdọ Batṣua ọmọbinrin Ammieli:
6
Abhari pẹlu, ati Eliṣama, ati Elifeleti,
7
Ati Noga, ati Nefegi, ati Jafia,
8
Ati Eliṣama, ati Eliada, ati Elifeleti mẹsan.
9
Wọnyi ni gbogbo awọn ọmọ Dafidi, laika awọn ọmọ àle rẹ̀, ati Tamari arabinrin wọn.
10
Ọmọ Solomoni si ni Rehoboamu, Abia ọmọ rẹ̀, Asa ọmọ rẹ̀, Jehoṣafati ọmọ rẹ̀.
11
Joramu ọmọ rẹ̀, Ahasiah ọmọ rẹ̀, Joaṣi ọmọ rẹ̀,
12
Amasiah ọmọ rẹ̀, Asariah ọmọ rẹ̀, Jotamu ọmọ rẹ̀,
13
Ahasi ọmọ rẹ̀, Hesekiah ọmọ rẹ̀, Manasse ọmọ rẹ̀,
14
Amoni ọmọ rẹ̀, Josiah ọmọ rẹ̀.
15
Ati awọn ọmọ Josiah; akọbi Johanani, ekeji Jehoiakimu, ẹkẹta Sedekiah, ẹkẹrin Ṣallumu.
16
Ati awọn ọmọ Jehoiakimu: Jekoniah ọmọ rẹ̀, Sedekiah ọmọ rẹ̀,
17
Ati awọn ọmọ Jekoniah; Assiri, Salatieli ọmọ rẹ̀.
18
Malkiramu pẹlu, ati Pedaiah, ati Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama ati Nehabiah,
19
Ati awọn ọmọ Pedaiah; Serubbabeli; ati Ṣimei; ati awọn ọmọ Serubbabeli; Meṣullamu, ati Hananiah, ati Ṣelomiti arabinrin wọn:
20
Ati Haṣuba, ati Oheli, ati Berekiah, ati Hasadiah, Juṣab-hesedi, marun.
21
Ati awọn ọmọ Hananiah; Pelatiah, ati Jesaiah: awọn ọmọ Refaiah, awọn ọmọ Arnani, awọn ọmọ Obadiah, awọn ọmọ Ṣekaniah.
22
Ati awọn ọmọ Ṣekaniah; Ṣemaiah; ati awọn ọmọ Ṣemaiah; Hettuṣi, ati Igeali, ati Bariah, ati Neariah, ati Ṣafati, mẹfa.
23
Ati awọn ọmọ Neariah; Elioenai, ati Hesekiah, ati Asrikamu, meta.
24
Ati awọn ọmọ Elioenai ni, Hodaiah, ati Eliaṣibu, ati Pelaiah, ti Akkubu, ati Johanani, ati Dalaiah, ati Anani, meje.
← Chapter 2
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 4 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29