bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
/
1 Chronicles 3
1 Chronicles 3
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
← Chapter 2
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 4 →
1
Àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ Dáfídì tí a bí fún un ní Hébírónì: Àkọ́bí sì ni Ámínónì ọmọ Áhínóámù ti Jésírẹ́lì; èkejì sì ni Dáníẹ́lì ọmọ Ábígáílì ará Kárímélì;
2
Ẹ̀kẹta sì ni Ábúsálómù ọmọ Mákà ọmọbìnrin ti Táímáì ọba Gésúrì; ẹ̀kẹrin sì ni Àdóníjà ọmọ Hágítì;
3
Ẹ̀kárùnún ni Ṣéfátíyà ọmọ Ábítalì; àti ẹ̀kẹfà, Ítíréàmù, láti ọ̀dọ̀ ìyàwó Rẹ̀ Égílà.
4
Ẹ̀kẹfà ni a bí fún Dáfídì ni Hébúrónì, níbi tí ó ti jẹ ọba fún ọdún méje àti oṣù mẹ́fà. Dáfídì sì jẹ ọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mẹ́talélọ́gbọ̀n (33).
5
Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ wẹ́wẹ́ tí a bí fún un: Ṣámúyà, Ṣóbábù, Náhátì àti Sólómónì. Àwọn mẹ́rin wọ̀nyí sì ni a bí láti ọ̀dọ̀ Bátíṣébà ọmọbìnrin Ámíélì.
6
Íbíhárì sì wà pẹ̀lú, Élíṣúà, Élífélétì,
7
Nógà, Néfégì, Táfíà,
8
Élísámù, Élíádà àti Élífétélì mẹ́sàn án ni wọ́n.
9
Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Dáfídì yàtọ̀ sí àwọn ọmọ tí àlè bí fún un. Támárì sì ni arábìnrin wọn.
10
Ọmọ Sólómónì ni Réhóbóhámù, Ábíjà ọmọ Rẹ̀, Ásà ọmọ Rẹ̀, Jéhósáfátì ọmọ Rẹ̀,
11
Jéhórámù ọmọ Rẹ̀, Áhásáyà ọmọ Rẹ̀, Jóásì ọmọ Rẹ̀,
12
Ámásáyà ọmọ Rẹ̀, Ásáríyà ọmọ Rẹ̀, Jótamù ọmọ Rẹ̀,
13
Áhásì ọmọ Rẹ̀, Hesekíáyà ọmọ Rẹ̀, Mánásè ọmọ Rẹ̀,
14
Ámónì ọmọ Rẹ̀, Jósíà ọmọ Rẹ̀.
15
Àwọn ọmọ Jósíà: Àkọ́bí ọmọ Rẹ̀ ni Jóhánánì, èkejì ọmọ Rẹ̀ ni Jéhóíákímù, ẹ̀kẹta ọmọ Rẹ̀ ni Ṣédékíà, ẹ̀kẹ́rin ọmọ Rẹ̀ ni Ṣálúmù.
16
Àwọn ìran ọmọ Jéhóíákímù: Jékóníà ọmọ Rẹ̀, àti Ṣedékíà.
17
Àwọn ọmọ Jéhóíákímù tí a mú ní ìgbékùn: Ṣálátíélì ọmọ Rẹ̀ ọkùnrin,
18
Málíkírámù, Pédáíyà, Ṣénásárì, Jékámíà, Hósámà àti Nédábíà.
19
Àwọn ọmọ Pédáíyà: Ṣérúbábélì àti Ṣíméhì. Àwọn ọmọ Ṣérúbábélì: Mésúlámù àti Hánáníyà, Ṣélómítì ni arábìnrin wọn.
20
Àwọn márùnún mìíràn sì tún wà: Hásúbà, Óhéhì, Bérékíà, Hasádíà àti Jusabi-Hésédì.
21
Àwọn ọmọ Hánáníyà: Pélátíà àti Jeṣáíà, àti àwọn ọmọ Réfáíà, ti Árínánì, ti Ọbadíà àti ti ṣékáníà.
22
Àwọn ọmọ Ṣékáníà: Ṣémáíà àti àwọn ọmọ Rẹ̀: Hátúsì, Ígéálì, Báríà, Néáríà àti Ṣáfátì, mẹ́fà ni gbogbo wọn.
23
Àwọn ọmọ Néáríà: Élíóéníà; Hísíkíà àti Ásírí kámù, mẹ́ta ni gbogbo wọn.
24
Àwọn ọmọ Élíóéníà: Hódáíà, Élíásíbù, Pétéláéà, Ákúbù, Jóhánánì, Déláyà àti Ánánì, méje sì ni gbogbo wọn.
← Chapter 2
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 4 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
Recommended Reading
Commentary
1 Chronicles Commentaries
→
Devotional
1 Chronicles Devotional Guide
→
Get This Bible
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní) Study Bible
→