bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
/
Job 35
Job 35
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
← Chapter 34
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 36 →
1
ELIHU sọ pẹlu o si wipe,
2
Iwọ rò pe eyi ha tọ́, ti iwọ wipe, ododo mi ni eyi niwaju Ọlọrun pe,
3
Nitoriti iwọ wipe, Ère kini yio jasi fun ọ, tabi ère kili emi o fi jẹ jù ère ẹ̀ṣẹ mi lọ?
4
Emi o da ọ lohùn ati awọn ẹgbẹ rẹ pẹlu rẹ.
5
Ṣiju wò ọrun, ki o ri i, ki o si bojuwo awọsanma ti o ga jù ọ lọ.
6
Bi iwọ ba ṣẹ̀ kini iwọ fi ṣe si i? tabi bi irekọja rẹ di pupọ, kini iwọ fi eyini ṣe si i?
7
Bi iwọ ba si ṣe olododo, kini iwọ fi bùn u, tabi kili on ri gbà lati ọwọ rẹ wá?
8
Ìwa buburu rẹ ni fun enia bi iwọ; ododo rẹ si ni fun ọmọ enia.
9
Nipa ọ̀pọlọpọ ininilara nwọn mu ni kigbe, nwọn kigbe nitori apá awọn alagbara.
10
Ṣugbọn kò si ẹniti o wipe, Nibo ni Ọlọrun Ẹlẹda mi wà, ti o fi orin fun mi li oru?
11
Ti on kọ́ wa li ẹkọ́ jù awọn ẹranko aiye lọ, ti o si mu wa gbọ́n jù awọn ẹiyẹ oju ọrun lọ.
12
Nigbana ni nwọn ke, ṣugbọn Ọlọrun kò dahùn nitori igberaga awọn enia buburu.
13
Nitõtọ Ọlọrun kì yio gbọ́ asan, bẹ̃ni Olodumare kì yio kà a si.
14
Bi o tilẹ ṣepe iwọ wipe, iwọ kì iri i, ọran idajọ mbẹ niwaju rẹ̀, ẹniti iwọ si gbẹkẹle.
15
Ṣugbọn nisisiyi nitoriti ibinu rẹ̀ kò ti ṣẹ́ ọ niṣẹ, on kò ha le imọ̀ ọ̀pọlọpọ ẹ̀ṣẹ bi?
16
Nitorina ni Jobu ṣe ya ẹnu rẹ̀ lasan, o sọ ọ̀rọ di pupọ laisi ìmọ.
← Chapter 34
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 36 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42